TO
O,
EKULE LAA K'ARA ILE O,
ERINWA LAA K'ERO ONA,
E LE NBEUN AJIDE ARA O
JE BII LAA K'ENI TOO SUN TO NA'PA NA'SE LE.
ADEWALE ARAKA,
MO DE
K'OLOKO O MA R'OKO WON LO,
MO DE K'OLODO O MA R'ODO.
A MO E SO FUN
GBOGBO ENI TI NGBOWO ODO KI WON O D'EKUN A A GBOWO ODO, GBOGBO OMO TI
NSUNKUN OMU O YE D'EKUN AA SUNKUN OMU.
MO DE P'ELOKODORO ORO,
NI IKORITA
IBI T'ORO BA GBE TA KOKO.
E O GBADUN TOBA. E NLE NBEUN
MO NBO UN KO TI DE
E KU IFOJUSONA...
No comments:
Post a Comment