Wednesday, 23 April 2014

ÌKÓRÍTA ÒKODORO ÒRÒ

TO O, 
EKULE LAA K'ARA ILE O, 
ERINWA LAA K'ERO ONA, 
E LE NBEUN AJIDE ARA O JE BII LAA K'ENI TOO SUN TO NA'PA NA'SE LE.
ADEWALE ARAKA, 
MO DE K'OLOKO O MA R'OKO WON LO, 
MO DE K'OLODO O MA R'ODO. 
A MO E SO FUN GBOGBO ENI TI NGBOWO ODO KI WON O D'EKUN A A GBOWO ODO, GBOGBO OMO TI NSUNKUN OMU O YE D'EKUN AA SUNKUN OMU. 
MO DE P'ELOKODORO ORO, 
NI IKORITA IBI T'ORO BA GBE TA KOKO. 
E O GBADUN TOBA. E NLE NBEUN
MO NBO UN KO TI DE
E KU IFOJUSONA...

Araka Presents Ewi for Historic EDE DAY 2013:



OLUWA WA AWA DUPE,
AWA YIN O OLUWA OBA TO NSOOHUN GBOGBO
AKII KITAN ELEDUMARE OBA L'OJO GBOGBO
KABIOKOSI OOO NI GBOGBO ILE KILE.

ADEWALE ARAKA EMI O SADEDE GB'ORI YIN F'OLORUN OBA
OORE GBOGBO,
GBOGBO OORE TO NSE FUN WA LO JE NFORIN B'ENU
KI NSE SADANKATA F'OBA ALAWURA.

GBOGBO OMO EDE MAPO AROGUN N'ILE L'OKO, LEHIN ODI
OPE LO YE WA OOO
AJODUN EDE DAY 2013 TUN S'OJU EMI WA
OLORUN OBA, AWA DUPE LOPOLOPO.

KAAABIESI, OBA WA MUNIRUDEEN ADESOLA, MUHAMMAD L'AWAL
LAMINISA AKOKO
ORUKO YI TI RO YIN PUPO O JARE
E MA MA PE MO BA YIN L'OYE MO PE YIN L'ORUKO
ORUKO NA FI NP'OBA ALADE
EJIGBA ILEKE NA FI NMO'LOYE LAAFIN
E KU ODUN, E KU IYEDUN ASEYI S'AMODUN
AS'AMODUN SEEMI
KA'JO MAA GBOHUN RIBIRIBI SE L'EDE TIWA,
ABURU KO NI F'OODE WA S'EBUGBE
A KUKU NI F'OSI LOGBA.

GBOGBO OMO EDE MAPO AROGUN
A RUN GBADO LA'LU
A RUN GUGURU W'OLE EDE
E NLE NBEHUN KAAJINDE O MA WA JE WA LOJUMO AYE GBOGBO
GBOGBO WA LAA PEJU S'OPOLOPO ODUN T'EBI T'ALARA WA
 O YA E BAMI S'AMIN GB'ETO AMIN MIN.

GBOGBO OTONKULU L'EDE MAPO NI MO KI PATA LAI D'ENIKAN SI OO
ADEWALE ARAKA
EMI OKUKU LOLODI KAN
F'ORO SIKUN BI AGBA OLOGBURO OBA AKORIN
ARAKA OMO OLA MI POO.

KESEKESE LEERI KASAKASA NBO L'ONA SE E FE E GBO
OHUN OTUN SESE BERE L'EDE MAPO AROGUN NI
MELO LAA FE KA L'EYIN ADIPELE
O YA E FUN MI LEESIN IBERE.

ADEWALE OMO LAOYE NLE OOO
E KU AKITIYAN PE KOLE DAA
OWO OTUN ADEWALE ARAKA NIYEN
LATI KEREKERE LAA TI D'IRA WA MU TA A SE'RA LOKAN
KA A PE E PE BI MOPE SE PE LOLA OBA OGA AGBA.

GBOGBO OMO EDE MAPO
E JE KA A D'IRA WA LOSUSU OWO
KA SERA WA LOKAN
KA A GBALAAFIA LAAYE KAJO MA A GBEPO NI YOTOMI.

A FENI TINA ORI E BA TI KU
NI SO O P'OLORUN O SE S'OHUN RERE FUN WA L'EDE
OPE LO YE WA PUPOPUPO.

A'IGBALAFIA LAAYE KO LE J'AYE O GUN
A'INIFE ARA DENU DENU
KII J'EYAN O R'ONA LO O DAMI L'OJU,
E JE A LO MO BE E.

O KU NI'KUN
O SEKU S'ENU
IPADE D'ORI PAPA NIBI AYEYE
KEE TO O GBO WIRIN~WIRIN L'ENU OBA AKORIN
BABASANYA ARAKA NI MI OLODE AKIKAWO
OJOOJUMO NI WON NBU NAIRA L'OJUDE BABA MI
ADEWALE OMO ADEGBITE L'ONFORIN TU KEKE EDE.....

Abiola Abioye KERIKERI Birthday

Congratulations Abiola Abioye KERIKERI HAPPY BIRTHDAY