Thursday, 18 September 2014

A P Á L A R Á!


MURA SISE RE ORE MI
ISE LA FI NDENI GIGA
BI A KO BA RENI F'EHINTI
BI OLE LA A RI
BI A OBA RENI GBEKELE
A TERA MOSE ENI
IYA RE LE E L'OWO L'OWO
BABA RE LE E L'ESIN L'EKAN
BI O BA GB'OJU LE WON
O TE TAN NI MO SO FUN E
APALARA IGUNPA NI Y'EKAN

Abiola Abioye KERIKERI Birthday

Congratulations Abiola Abioye KERIKERI HAPPY BIRTHDAY